OBE EYONU TODARA

Ewe ominsinminsin gogoro oojo,, Ao lo pelu iyere die, Ao fi se eyin adie meta je lepo niyo..
NB: Ao koko bo eyin naa kia to fise aseje naa..
(2) Ti a ba lo ewe yati iyere naa tan, atun le fo eyin meta si kia ro sinu nylon, kia se jinna.. jije pelu Adura lopolopo,, Eyonu Gidi naa ni.. Osise daada!!!

Comments

  1. E kaaro sir, a juu yin see o baba, e jowo mo nilo iranlowo yin nipa oro aye mi ni o. Ero ibanisoro mi niyi 08072637577

    ReplyDelete

Post a Comment

Popular posts from this blog

Ogun Atude or Ebe awon agba

Ogun agbelepota

Ose Osole owo