Ogun Atude or Ebe awon agba

E jowo e ba mi dan ise yi wo. Ogede omini to pon dada meta, atare odidi meje, ao bo ogede omini yi, ao wa yo omo atare yen si bi kan. Ao wa ma fi ogede omini yen ba atare yi, ni gbogbo ara re, ao se ogede meta be. Ti a ba ti se tan, ao wa fi odo ti won fi gun iyan bo ogede yen ti ojo keji. Ao wa ko ogede meta yi sinu agbada, ao wa jo. Ti a ba ti jo tan, ao wa lo ti yio kuna dada. Ao wa da sinu igo funfun. Lilo re: ao wa ma bu si eyi owo, ao wa ma fi owo gba yio si ma wole pelu ase olorun. Ki e to lo ise kan e o koko se ise yi fun eni na. Ti e ba fun eni na omi lasan pe kolo lo yio sise fun.

Comments

Post a Comment

Popular posts from this blog

Ogun agbelepota

Ose Osole owo