Ose Osole owo
EWE BARA OOJO 9,E GUN KUNNA PELU ERU ALAMO IYEKIYE,KIE WA POMO OSE,KI E WA FI EJE EIYELE FUNFUN BALAU PO OSE YI DAADAA,KI E WA KO OSE YI SI INU IGBA OLOMORI,KI E WA GBE PAMO FUN 16days GBAKO.LEYIN NAA O DI WIWE LARARO NIYEN..PELU OGO OLOHUN OWO GIDI NI WON YIO MAA GBEWA..but IKILO...enikeni ko gbodo ri igba yi nibi ti a ba gbesi ooo titi ti ojo naa yio fi peooo.TI E BA TI PARI ISE YEN TAN KI E WA LO BO EIYELE YI MOLE SORI AKITAN...
Ejowo ti eyan Bari nibi ti agbe iṣẹ yen si kilo ma sele
ReplyDeleteCall me chief priesthood on how to do a money rituals 08141773658, tabi fun ISE Ogun owo gbewa nla
ReplyDeleteAm going to do it
ReplyDeleteWhat is the repercussions sir??
ReplyDeleteThank you sir
ReplyDeleteThanks so much and godbless you,
ReplyDelete