Posts

Showing posts from October, 2020

ASIRI BIBO OWO

Ao fi owo tuntun nla kan tele ape, ao fi eku asin gbigbe kan, oga gbigbe kan, atare kan le lori, Ao wa fi owo wa mejeji bu iresi tutu le lori leekan soso.. Jijo po.. Ao maa fi hot lo laro laro pelu adura asiri bibo owo..

APORO TO SISE

Gbogbo ifun inu akuko adie togbo daada, ewe papasan oojo,, Ao gun mejeji kunna daada, Ao ko sinu keg nla kan, Ao da adi eyan le lori..Ao bere silo ni ojo keeta.. Lilo re: Sibi meji laro nikan fun ofa ara,, sibi meji laro ati ale fun awon aisan ara miran..

OBE EYONU TODARA

Ewe ominsinminsin gogoro oojo,, Ao lo pelu iyere die, Ao fi se eyin adie meta je lepo niyo.. NB: Ao koko bo eyin naa kia to fise aseje naa.. (2) Ti a ba lo ewe yati iyere naa tan, atun le fo eyin meta si kia ro sinu nylon, kia se jinna.. jije pelu Adura lopolopo,, Eyonu Gidi naa ni.. Osise daada!!!

ASINA AJIFA:

  Ewe etiponola 201, ao ge owo tuntun si 201, iyere 201, iru 201,, lilo po, ao fi se aseje pelu eran malu tia gesi 201 lepo niyo..NB: Oti ni ao fi se omi re tia ba nse, omi ko gbodo kan oo,, ao mu oti le tia ba je tan.. Odaju!!!

AROBI DANU SORI OTA

“ Aja ti motor ba gba leekan naa ti igbe si jade nidi re leekan naa,, Ao mu igbe naa, Ao jo pelu odindin atare kan, Ao po mo ori.. Lilo re: Ao maa fi Oogun yi ra idodo wa ni aro/ale tabi nigbakugba.. Odaju gan!!!

Ogun Eyoun Awon Agba Todaju

A O Wa Eepo Epa Ti Won Dasi Ori Tameta A O wa Lo Bu Die Niu Re Atare Odidi Kan A O Jopapo A O Ma Fifo Eko Mu ,2 Ao Wa Eepo Eyin Adie Abalaye Die Pelu Sugar Oni Koro Ati Oyin Gidi Ao Lopo Ao Mafi Oyin Lo Pelu Ofore ,bi Adie Bayin Ehin Enu Ni Fin Tunse Eyin Aye Efi Ohun Rere Tun Mise

OGUN EYONU GIDI:

E je kia lo wa Eso ewedu lopolopo, kia lo kunna daada, pipo mo ori, ao maa fi ra idodo wa ti a ba n jade lo, pelu opolopo adura.. Ogo Olorun ni o!!!

Awure owo

 Egbo iroko, egbo ipon, karagba idi esu, ose dudu, ao gun gbogbo re po, ao ma fi we lararo., gbolohun: “ipon loni kan pinre temi fun mi loni, iroko loni afaro.

Asiri bibo Owo

Ewe iyalode funfun(7) ao fi te le koko…ao wa asin pelu N1000 aganran pelu odindin atare kan ao wa ko si inu re..ao wa da ewe iyalode pupa (7) lori….ao wa jo papo nigba ti a njo ao da epo pupa yika aro ina ti a da….ti o ba jo tan a fi fo eko tutu mu ni alalale