ELO WA EFUN,OSUN,EDU,KIE LO METEETA PAPO MO OSE DUDU,KI E WA FI OSE DUDU YI TEFA EJI OGBE SI OJU OLO,KIE WA PE OHUN RE SI BAYI::EFUN LERIPE OHUNYIO BATI OSUN JE,OSUN LERIPE OHUN YIO BATI EFUN JE,ATI EFUN,ATI OSUN,EDU NIO BATI GBOGBO WON JE,GBOGBO ENITOBARO IBI RO EMI L OMO L,KIBI WON PADA SODO WON.AO KO OSE YI SINU IKE KAN,AO MAA WE LALELALE TI A BA TI FE SUN
E jowo e ba mi dan ise yi wo. Ogede omini to pon dada meta, atare odidi meje, ao bo ogede omini yi, ao wa yo omo atare yen si bi kan. Ao wa ma fi ogede omini yen ba atare yi, ni gbogbo ara re, ao se ogede meta be. Ti a ba ti se tan, ao wa fi odo ti won fi gun iyan bo ogede yen ti ojo keji. Ao wa ko ogede meta yi sinu agbada, ao wa jo. Ti a ba ti jo tan, ao wa lo ti yio kuna dada. Ao wa da sinu igo funfun. Lilo re: ao wa ma bu si eyi owo, ao wa ma fi owo gba yio si ma wole pelu ase olorun. Ki e to lo ise kan e o koko se ise yi fun eni na. Ti e ba fun eni na omi lasan pe kolo lo yio sise fun.
Omo araiye koni mun wa tomo tomo, taya taya, toko toko, Ohun isora ti a maa nfi ewe Koko se ni eleyi, tori opo loti te ogun buruku mole, ti elomiran ti paralyze ti o ba lo ti o ba bo, won ani awon agba lo wa ni idi re besi ko ole je wipe awon Ore ti o nbinu re lo da unkan si oju ese re lati lefi ba carrier eni naa je,.. Ejeki a lo ewe ti e nwo aworan re yii fun isora yii, Ao ja ewe kan ni inu ewe yii ao gbe ese otun waa le lori, ao fi razor blade yo size ese waa ninu ewe yii, ao jo pelu oko atare kan, gbere yii ese otun kaa, ao tun ja ewe kan lara ewe naa ao tun sebe si ese alafia, ao tun jo pelu oko ataare kan, gbere yii ese alafia kaa
God Almighty bless you
ReplyDeleteEwe amaje thank you
ReplyDelete