E jowo e ba mi dan ise yi wo. Ogede omini to pon dada meta, atare odidi meje, ao bo ogede omini yi, ao wa yo omo atare yen si bi kan. Ao wa ma fi ogede omini yen ba atare yi, ni gbogbo ara re, ao se ogede meta be. Ti a ba ti se tan, ao wa fi odo ti won fi gun iyan bo ogede yen ti ojo keji. Ao wa ko ogede meta yi sinu agbada, ao wa jo. Ti a ba ti jo tan, ao wa lo ti yio kuna dada. Ao wa da sinu igo funfun. Lilo re: ao wa ma bu si eyi owo, ao wa ma fi owo gba yio si ma wole pelu ase olorun. Ki e to lo ise kan e o koko se ise yi fun eni na. Ti e ba fun eni na omi lasan pe kolo lo yio sise fun.
ELO WA EFUN,OSUN,EDU,KIE LO METEETA PAPO MO OSE DUDU,KI E WA FI OSE DUDU YI TEFA EJI OGBE SI OJU OLO,KIE WA PE OHUN RE SI BAYI::EFUN LERIPE OHUNYIO BATI OSUN JE,OSUN LERIPE OHUN YIO BATI EFUN JE,ATI EFUN,ATI OSUN,EDU NIO BATI GBOGBO WON JE,GBOGBO ENITOBARO IBI RO EMI L OMO L,KIBI WON PADA SODO WON.AO KO OSE YI SINU IKE KAN,AO MAA WE LALELALE TI A BA TI FE SUN
EWE BARA OOJO 9,E GUN KUNNA PELU ERU ALAMO IYEKIYE,KIE WA POMO OSE,KI E WA FI EJE EIYELE FUNFUN BALAU PO OSE YI DAADAA,KI E WA KO OSE YI SI INU IGBA OLOMORI,KI E WA GBE PAMO FUN 16days GBAKO.LEYIN NAA O DI WIWE LARARO NIYEN..PELU OGO OLOHUN OWO GIDI NI WON YIO MAA GBEWA..but IKILO...enikeni ko gbodo ri igba yi nibi ti a ba gbesi ooo titi ti ojo naa yio fi peooo.TI E BA TI PARI ISE YEN TAN KI E WA LO BO EIYELE YI MOLE SORI AKITAN...
Comments
Post a Comment