Posts

Showing posts from July, 2019

Ogun Ife

Ewe odan 9 Ewe iyeye 9 Ao gun papo Mon ose dudu... Ofo re ni yii ...... Oju ewure kin si Lara ewe odan , oju aguntan kin si Lara iyeye, Iwo L Omo L ki oju re maa se si Lara emi L Omo L loni .....confirm ni

IPESE FUN ASIRI BIBO OWO

Ibepe ti eiye jeku lori igi ao ja ti koni kanle, ao jo mon odidi atare kan, eso idooo iyekiye ao jo mon odidi atare kan lototo nio ao wara akara elepo meta ao bu etu nan si oru akara nan ao da epo si ao wure ohun ti a ba fe si ao gbe sorita ti won ba gba dandan ni ki ari ohun ti a ba fe.

Asina atube

Eku asin 3.egbo tude topo.epo obo die pelu odidi atare kan a o jo po..ti a bafe lo a o te ni ifa osa eleye..ofo re..odere ori iroko.eiye aiye tike kaa kaa kaa.sebi eyin ni e ran eku asin ni ise.e sope ekukeku ko gbodo dena de eku asin.e sope eku toba dena de eku asin jinnijinni a se won.eniba fe dena ore aye mi.ki jinnijinni o se won o.tude wa tude ara emi - omo- ki o wa sina owo nlanla fun mi o.a o fi oti regal tabi schinap lo..

Ogun Atude or Ebe awon agba

E jowo e ba mi dan ise yi wo. Ogede omini to pon dada meta, atare odidi meje, ao bo ogede omini yi, ao wa yo omo atare yen si bi kan. Ao wa ma fi ogede omini yen ba atare yi, ni gbogbo ara re, ao se ogede meta be. Ti a ba ti se tan, ao wa fi odo ti won fi gun iyan bo ogede yen ti ojo keji. Ao wa ko ogede meta yi sinu agbada, ao wa jo. Ti a ba ti jo tan, ao wa lo ti yio kuna dada. Ao wa da sinu igo funfun. Lilo re: ao wa ma bu si eyi owo, ao wa ma fi owo gba yio si ma wole pelu ase olorun. Ki e to lo ise kan e o koko se ise yi fun eni na. Ti e ba fun eni na omi lasan pe kolo lo yio sise fun.

Ogun basiri

Ewe ewuro oojọ , aolọpọ aofi kafura pẹlẹbẹ odindin kan si aofi ọṣẹ ko lori ọlọ Aoko sinu ike funfun kan Aomafiwẹ

Osole atube

ako alangba mesan ao to sinu ape ao to atare Mesan yipo ao ko idi egbo tude mesan le lori ao Jo ao mafi oti lo o daju gan

OGUN GBETUGBETU

Ao toju owo èyo mèwa ti ko luju, ewe daiko, ewe alupaida èyo meje, ewe orira, odidi atare kan, ao lo awon ewe yèn papo pèlu odidi atare yè, ao toju omo diè to ba sonu lèyin iya rè kan, ao wa la adiè na ni aya, ao bu ogun ti alo yè si ni isalè, ao ko owo èyo le lori, ao wa da ogun yoku le owo èyo lori. Awa de pa mo ara won, awa di papo, ao fi ora yi , ao di ni okun dada ti yio fi jè wipe omi ko le wo inu rè ti aba bo mo inu odo. Odo ti nba nsan dada ni abo mo fun ojo meje. Awa toju aso ipa odè, ao ran ni apo kekere, ti obadi ojo keje, ti aba wu ogun yen ni inu odo, ao ko owo èyo yèn sinu apo ti aran yèn. Lilo rè: ao mun èyo owo èyo kan lowo, ti aba ri awon ole tabi dana-dana, ao ma wa pe ofo rè bayi pe: daiko ki odari won lugbo, orira ki ora won niye, alupaida loni ki won o ma pa oro mi da, èri ki san ko boju wo èyin. Awa na owo wa sinu igbo pe ki won olo ba owa kinni ti oju nu. Awa so owo èyo yè si apo pada. Ako ni ju owo èyo yè si inu igbo, ao kan na owo wa si igbo lasan ni o.

Obinrin tobimo tan ti ejekoda

Eko elewe ao bo ewe arare ao bu okele Kan nibe ao fi kan die lara eje yen ao so si enu obinrin naa Walahi eje naa yoo da ni kiakia

Ajegun

Ase oga Ewe alupaida mesan eyo atare mesan ao lo po aofi Singbere yipo orun owo wa Eyan kan lolelo odaju

Awure itaja

Ako alangba ESO werenjeje aorosi lenu aofi lagba tele ape aoko ewe werejeje lelori pelu odidi atare kan aojopo aomafi eko lolaro epo pupa lale

Asina

Ao wa owo eyo eyiti ko luju rara ,ao fi ko jankariwo to akoni ri sowo eyo yi Nita rara ao wa gun mo ose ise ekan soso ao jilo we fiwe ni odo to nsan ni arokukutu ni oooo

ARANSE ATI ASINA

ARANSE KIAKIA: Ori pepeye ako kan, odidi atare kan, ewe sawerepepe, oka burumo pelu haha re ao jopo ao ma fi oti laro ASINA: Koro ishin kopo die, ao Jo ao ma fi fo eko mu laaro. Odaju

Asina

ewe taba 7 atare eyo 7 a o mu ewe 1 atare1 a o Lo ni enu ona so fi ose ti a le Lo lekan soso ko,ao se be titi ti yio fi pe meje ao MA we ni ojo kankan Tio fi pe ojo meje,ojo meje lowa ninu ose kan eni to ba le gbiyanju e Loni a dupe fun Olohun ni ose ti a ba Lo ise Yi

Ogun agbelepota

ELO WA EFUN,OSUN,EDU,KIE LO METEETA PAPO MO OSE DUDU,KI E WA FI OSE DUDU YI TEFA EJI OGBE SI OJU OLO,KIE WA PE OHUN RE SI BAYI::EFUN LERIPE OHUNYIO BATI OSUN JE,OSUN LERIPE OHUN YIO BATI EFUN JE,ATI EFUN,ATI OSUN,EDU NIO BATI GBOGBO WON JE,GBOGBO ENITOBARO IBI RO EMI L OMO L,KIBI WON PADA SODO WON.AO KO OSE YI SINU IKE KAN,AO MAA WE LALELALE TI A BA TI FE SUN

IMULE EBE AWON AGBA (Idarijin Awon Eleye)

Mofe kiaje anfani yi, ni ki Ona letete si funwa nidi Ise ti anse, ati Ninu Irin ajo eda, Ema tele mi............ Ewe Orijin oojo 16, Ewe Ewuro oojo 16, Ewe Lapalapa funfun Oojo 16, Eru alamo 16, Epo obo die, Igi nla die, Ao gun gbogbo repo mo Ose dudu, Ao kosinu fitila Oloju 16, Tia ba kosi fitila na tan, Kogbodo kanle mo, Tiao filo Ose yitan, Ao mafiwe ni Araro ati alale, Odaju ganniooo ,Ebe ati Imule Idarijin awon Eleye to Confirm niooo, IKILO: Tia batinwe Ose yi kanhinkanhin re ko gbodo jabo, Bi abatin lo Ose yi, Akogbodo je Eran Abiye kankan mo, bi Pepeye, Eyele, Adiye, Turkey, Adan, Eye etu, Tiaofilo tan, Nitori Imule OSA-MEJI Nla tolagbara ni, Ako gbodo tunje Eran kankan namo, besini, ti abalotan ni ao ma je eran,Leyin ni ti aba gbagbe lati je Eran.Ao da Ose na duro na,Agbudo se Etutu si Nitori,Ki ama bari Ija Eleye

Ogun isora

Omo araiye koni mun wa tomo tomo, taya taya, toko toko, Ohun isora ti a maa nfi ewe Koko se ni eleyi, tori opo loti te ogun buruku mole, ti elomiran ti paralyze ti o ba lo ti o ba bo, won ani awon agba lo wa ni idi re besi ko ole je wipe awon Ore ti o nbinu re lo da unkan si oju ese re lati lefi ba carrier eni naa je,.. Ejeki a lo ewe ti e nwo aworan re yii fun isora yii, Ao ja ewe kan ni inu ewe yii ao gbe ese otun waa le lori, ao fi razor blade yo size ese waa ninu ewe yii, ao jo pelu oko atare kan, gbere yii ese otun kaa, ao tun ja ewe kan lara ewe naa ao tun sebe si ese alafia, ao tun jo pelu oko ataare kan, gbere yii ese alafia kaa

Ose Osole owo

EWE BARA OOJO 9,E GUN KUNNA PELU ERU ALAMO IYEKIYE,KIE WA POMO OSE,KI E WA FI EJE EIYELE FUNFUN BALAU PO OSE YI DAADAA,KI E WA KO OSE YI SI INU IGBA OLOMORI,KI E WA GBE PAMO FUN 16days GBAKO.LEYIN NAA O DI WIWE LARARO NIYEN..PELU OGO OLOHUN OWO GIDI NI WON YIO MAA GBEWA..but IKILO...enikeni ko gbodo ri igba yi nibi ti a ba gbesi ooo titi ti ojo naa yio fi peooo.TI E BA TI PARI ISE YEN TAN KI E WA LO BO EIYELE YI MOLE SORI AKITAN...

Typhoid and malaria

PINEAPPLE PEEL LIME 9PIECE ORANGE 2BIG SIZE LEMON GRASS LEAF GINGER 2BIG SIZE GARLIC 10 SMALL PIECE 5lipton tea bag CORN WATER (omi dun in Yoruba) Cooked all together, took 1cup to bed and I work up feeling relief, passing it out tru urine. Dosage 1cup 3x daily.